Oyo 2019: OCF ends tour for Governor in Iseyin, also read in Yoruba

Oyo 2019: OCF ends tour for Governor in Iseyin

 

As agitation for the Agodi landlord continues,
Political Leaders from the Okeogun region of Oyo State, under the aegis of Okeogun Consultative Forum rose from their maiden conference ranging from all Councils in the Okeogun area and ends their sensitisation meeting in Iseyin on Saturday with a resolve that it would be the turn of Okeogun to produce the next governor of the state come 2019.

They also advised all registered political parties in the state to take into consideration their demands in the choice of governorship candidates in 2019, insisting that for there to be a continued sustenance of peace, stability, and progress in 0yo State, there was need to maintain equity, fairness and justice in governance.

The finale netting was held at the Iseyim City Hall where in attendance the who is who from Okeogun area.

 

In attendance were aspirants such as Professor Adeolu Akande, Engineer Remi Olaniyan, Mr Deboh Adeshina among others.

••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••••

 

Translation

 

Yoruba

 

Ọ̀yọ́ 2019: OCF dópin ìrìn -àjò fún Gómìnà ní Ìṣẹ́yìn

 

Bí ìdààmú fún aláfitì Agodi ṣe ń tẹ̀síwájú, Olùdarí Olóṣèlú láti Òkè Ògùn ti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, lábẹ́ àwọn ìsè dúró ti òkè-ògùn Consultative Forum dìde láti pe àpèjọ wọn àti pé Wọ́n ti parí iṣẹ́ wọn ní Ìṣẹ́ yìn ní ọjọ́ Àbámẹ́ta yìí pẹ̀lú ìpinnu pé, wọn yóò jẹ́ òpó Òkè-ògùn láti gbé àwọn Gómìnà ti ìpínlẹ̀ náà wá ní 2019.

Wọ́n tún níyànjú fún gbogbo àwọn olóṣèlú tí a forúkọ ṣílẹ̀ ní ìpinnu láti ṣe àkíyèṣí àwọn ìbéèrè wọn ní ìpinnu àwọn olùdìbò olùdíje ní ọdún 2019,tẹnu mọ pẹ̀lú ìdánilójú pé láti jẹ́ kí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ wà ní àlàáfíà, ìdúró ṣinṣin àti ìlosíwájú. Wọ́n nílò ìṣe déédéé, ìnífura, àti ìdájọ́ òdodo ní ìjọba.

Fífi àdàgbá ètò rọ̀ wáyé ní Gbọ̀ngàn ìlú Ìṣẹ́yìn, níbi tí àwọn èèkàn èèkàn láti agbègbè òkè-ògùn ti wà ní ìjókòó.

Lára àwọn olùdíje tí wọ́n wà ní ìjókòó ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Adeolu Akande, Onímọ̀ Ẹ̀rọ Remi Olaniyi, Ọ̀gbẹ́ni Debo Adesina, abbl.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

%d bloggers like this: