ORIKI SAKI!!!!!

Saki Ogun o ro kin,
Agbede o ro baba,
Asabari o koja,
Oloogun o kare,
B’o ba dojo ija ka ran eni Sasabari,
B’o ba dojo ere ka ran eni S’oloogun
Saki Arogun yo,Omo afogunsowo se,
Eni ti ko bale ja ko ma se ba wa da sa kan a n gbe Saki,
Nitori Ogun nise won.
Beere ki o to wo
Ki o ma ba saa gijogijo bo ba dojo ogun
Alaluwon! Abalakubolo..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

%d bloggers like this: