ORIKI IDILE BAKOJA

• “Baby girl” “my love” “pretty girl” “gorgeous” “beautiful” are names that make many heart happy.

Image result for eulogy

Here is the ORIKI IDILE BAKOJA that makes the Bakojas always happy :

Omo ekun benuje.

Omo olodo n kuse.

Omo amuni labe ekuku.

Omo ababa tiriba elete koraye pa loju.

Eni,eyi eni ni won ngbin-moran, ika

Omo egungun jelede o ferin si.

Egungun naa ni fi aso oran gbale gerere.

Omo Atanda o lofi gbami.

Moninuola oye ngbemi lo.

O wonso parapara bomo agbe lorun.

Bo dele Atanda, bo ‘ba Atanda nile.

Moninuola sinsin aso ni dawo ni pele.

Omo ori fo agbe, ni mogun.

Omo ori fo agbe, ni mogun.

Omo a to bo loju ogun.

Omo subu subu talawo ojo telepo.

Ibi oniyomoti subu nbe lo ta tan.

Boya elepo a ridie ni ibi ti won.

Won o ridie nibi tatanda.

Ogboko ogbodo lowo won.

Gbogbo eniyan ni won agbon losi.

Balokoja Omo olodo ide.

Emo nawa ni sale osi.

Eni to bawa dele osi ni muja wa.

Eni to bawa dele Bakoja ni wa apon kiri.

Omo iku oti.

Omo alukete.

Omo Amori eleku nla.

A daso male e gbe.

Omo Amori elekun loge.

 

Get more stories like this on Twitter & Facebook

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

%d bloggers like this: